Meet your new press agentNípa

Publish


Ó wànílẹ̀ ni ibi tí ó pọ̀ju àwọn orílẹ̀-èdè 160 lọ ati awọn èdè ìkọ̀ọ̀kan wọn, Kontax n gba àwọn oníìbárà ti ilé-iṣẹ́ ati ti àwọn ibi tí a ṣàgbékalẹ̀ ní gbogbo orilẹ-ede laaye lati ṣatẹjade iye àwọn agbejade iroyin aláìlódiwọ̀n ní èdè tí wọn yàn, ati lati gba awọn agbejade iroyin ni awọn èdè eyikeyii miran tí akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ túmọ̀.

Translate


Àwọn olùmúlò n ní ìkànsíraẹni tààrà pẹ̀lú awọn ilé-iṣẹ atúmọ̀-èdè alábàáṣiṣẹ́pọ̀ ti Kontax – eyiti púpọ̀ ninu wọn ní ìwé-ẹrí ISO 9001 tabi eyiti o rí bákan náà bíi rẹ̀, atipe gbogbo wọn n ṣe àmúlò awọn igbeṣẹ ìfọwọ́ṣọ̀yà fun pípéye ti EN 15038 – atipe a ti yàn wọ́n ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan lati ríi dájú pé àwọn agbejade iroyin tí a túmọ̀ sí èdè miran ni a ti ṣàmúlò bótiyẹ nípa ti iye owó níná ati ti pípéye gíga..

Distribute


Tí a pín fún awọn oníròyìn ati awọn ibi agbejade ìbáṣepọ̀ káàkiri àgbáyé náà, tí a n ṣàmúlò bótiyẹ fún awọn ẹ̀rọ ìṣèwádìí ni gbogbo orilẹ-ede, Kontax túmọ̀ sí wipe àwọn olùmúlò leè polówó awọn ọjà wọn, ta àwọn iṣẹ́ wọn, mú awọn alábàáṣiṣẹ́pọ̀ wọn, kí wọ́n sì ṣamojuto àwọn ọjà káàkiri àgbáyé.

Àwọn Iṣẹ́

  Publish
12 EUR

 • Ṣíṣe atẹjade awọn agbejade iroyin ni èdè naa ati ẹka imọ naa ti o fẹ láláìsanwó

 • Àwọn agbejade iroyin ọlọpọ ọna ìṣàgbéjáde iroyin (Àwọn fídíò YouTube, àwọn aworan …)

 • Àyọkà tabi ọrọ alailodiwọn

 • Ìlànà Eto Ìṣàkóso Agbejade Iroyin ti Ìwànípo Ayelujara Tópé Pérépéré

 • Imuṣiṣẹpapọ aládàáṣiṣẹ ti awọn agbejade iroyin ni inú awọn ibi ibaṣepọ tó ń siwaju kaakiri agbaye

 • Ìṣàmúlò Ẹrọ Aṣèwádìí Bótiyẹ (SEO) ti awọn agbejade iroyin

 • Tí ó ṣeé wọlé sí lori awọn ẹrọ alágbèéká ati awọn aláfọwọmú

  Translate
110 EUR

 • Iye owó itumọ sí èdè míràn tí ó rọrùn nitori awọn ilé-iṣẹ atumọ-èdè tówà ní orilẹ-ede naa
 • Títúmọ si awọn èdè miran ni a ń ṣe nipaṣẹ ìtàkùn awọn ilé-iṣẹ atumọ-èdè tiwọn ní ìwé-ẹrí ISO 9001 tabi eyiti o rí bákan náà bíi rẹ kaakiri agbaye
 • Àwọn itumọ ti awọn agbejade iroyin wànilẹ ni àwọn orilẹ-ede tí ó ju 160 lọ àti ní àwọn èdè ìkọọkan wọn
 • Ikansiraẹni tààrà pẹlu ilé-iṣẹ atumọ-èdè náà tí a fi fún orilẹ-ede rẹ
 • Ìfọwọṣọya fun iṣẹ tópéye

  Distribute
149 EUR

 • Targets include 900,000 journalists
 • Readership by a minimum of 2,000 journalists guaranteed
 • Formatting compliant with Newswire standards / NewsML standard indexing
 • Real-time readership statistics/ Detailed reporting

  Track
0 EUR

 • Market Monitoring in all languages, countries, and market sectors
 • Àwọn kíkọ síi RSS nipaṣẹ ẹ̀ka ìmọ ati èdè
 • Àwọn ìtanijí Agbejade Iroyin (AI) – wanilẹ nipaṣẹ ìlú, orilẹ-èdè, ẹka imọ, ati kókó ọrọ
 • Iye nọmba wíwò fun AI kọọkan nipaṣẹ orilẹ-èdè
 • Ìlànà eto Ibi Ìpamọ ati Ìṣèwádìí ni gbogbo àwọn èdè pàtàkí

Here’s how Kontax optimizes the global impact of your press releases:


  When you publish a press release, Kontax sends you an alert by e-mail. Forward it to your friends, customers and prospects, for greater social impact!


To translate a press release, go to your User panel, select the press release and click on the "Translate" icon : Your Kontax Translation Manager will take care of the rest. In a global economy, this optimizes its international impact.

To distribute a press release, go to your User Panel, select the press release and click on the "Distribute" You control the date of distribution, to optimize its impact in time.

To optimize their global impact, your press releases (and translations) are automatically

included in the multilingual daily alerts and weekly newsletters sent to Kontax users,

included in the RSS feeds generated by Kontax,

relayed by Kontax to social media such as Twitter, Facebook etc.